An-Nisa · 119/176
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Nisa
وَلَأُضِلَّنَّهُمْ وَلَأُمَنِّيَنَّهُمْ وَلَآمُرَنَّهُمْ فَلَيُبَتِّكُنَّ آذَانَ الْأَنْعَامِ وَلَآمُرَنَّهُمْ فَلَيُغَيِّرُنَّ خَلْقَ اللَّهِ ۚ وَمَن يَتَّخِذِ الشَّيْطَانَ وَلِيًّا مِّن دُونِ اللَّهِ فَقَدْ خَسِرَ خُسْرَانًا مُّبِينًا ۝١١٩
Wa la udillannahum wa la umanni yannnahum wa la aamurannahum fala yubat tikunna aazaanal lan`aami wa la aamurannahum fala yughai yirunna khalqal laah; wa mai yattakhizish Shaitaana waliyyam mmin doonil laahi faqad khasira khusraanam mubeena
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju mo maa si won lona. Mo maa fi erokero sinu okan won. Mo maa pa won lase, won yo si maa ge eti eran-osin (lati ya a soto fun orisa). Mo maa pa won lase, won yo si maa yi eda Allahu pada." Enikeni ti o ba mu Esu ni ore leyin Allahu, dajudaju o ti sofo ni ofo ponnbele
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 117-121 — An-Nisa

117إِن يَدْعُونَ مِن دُونِهِ إِلَّا إِنَاثًا وَإِن يَدْعُونَ إِلَّا شَيْطَانًا مَّرِيدًا
Won ko pe kini kan leyin Allahu bi ko se awon abo orisa. Won ko si pe kini kan bi ko se Esu oluyapa
118لَّعَنَهُ اللَّهُ ۘ وَقَالَ لَأَتَّخِذَنَّ مِنْ عِبَادِكَ نَصِيبًا مَّفْرُوضًا
Allahu sebi le Esu. O si wi pe: "Dajudaju mo maa mu ipin ti won pin fun mi ninu awon erusin Re
119وَلَأُضِلَّنَّهُمْ وَلَأُمَنِّيَنَّهُمْ وَلَآمُرَنَّهُمْ فَلَيُبَتِّكُنَّ آذَانَ الْأَنْعَامِ وَلَآمُرَنَّهُمْ فَلَيُغَيِّرُنَّ خَلْقَ اللَّهِ ۚ وَمَن يَتَّخِذِ الشَّيْطَانَ وَلِيًّا مِّن دُونِ اللَّهِ فَقَدْ خَسِرَ خُسْرَانًا مُّبِينًا
Dajudaju mo maa si won lona. Mo maa fi erokero sinu okan won. Mo maa pa won lase, won yo si maa ge eti eran-osin (lati ya a soto fun orisa). Mo maa pa won lase, won yo si maa yi eda Allahu pada." Enikeni ti o ba mu Esu ni ore leyin Allahu, dajudaju o ti sofo ni ofo ponnbele
120يَعِدُهُمْ وَيُمَنِّيهِمْ ۖ وَمَا يَعِدُهُمُ الشَّيْطَانُ إِلَّا غُرُورًا
Esu n sadehun fun won, o si n fi ife-iro sinu okan won. Esu ko si sadehun kan fun won bi ko se etan
121أُولَٰئِكَ مَأْوَاهُمْ جَهَنَّمُ وَلَا يَجِدُونَ عَنْهَا مَحِيصًا
Awon wonyen, ina Jahanamo ni ibugbe won; won ko si nii ri ibusasi kan
An-NisaAtokọ Kurani
176Ẹsẹ
MedinanRevelation
119Ẹsẹ

Itumọ — An-Nisa 119

Surah An-Nisa Ẹsẹ 119 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju mo maa si won lona. Mo maa fi erokero…

Surah Ẹsẹ 119/176 — An-Nisa النساء (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Nisa Gbọ, An-Nisa Itumọ, An-Nisa mp3, An-Nisa pdf. Ẹsẹ 117–121. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers