An-Nisa · 120/176
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Nisa
يَعِدُهُمْ وَيُمَنِّيهِمْ ۖ وَمَا يَعِدُهُمُ الشَّيْطَانُ إِلَّا غُرُورًا ١٢٠
Transliteration
Ya`iduhum wa yuman neehim wa maa ya`iduhumush Shaitaanu illaa ghurooraa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Esu n sadehun fun won, o si n fi ife-iro sinu okan won. Esu ko si sadehun kan fun won bi ko se etan
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 118-122 — An-Nisa
118لَّعَنَهُ اللَّهُ ۘ وَقَالَ لَأَتَّخِذَنَّ مِنْ عِبَادِكَ نَصِيبًا مَّفْرُوضًا
Allahu sebi le Esu. O si wi pe: "Dajudaju mo maa mu ipin ti won pin fun mi ninu awon erusin Re
119وَلَأُضِلَّنَّهُمْ وَلَأُمَنِّيَنَّهُمْ وَلَآمُرَنَّهُمْ فَلَيُبَتِّكُنَّ آذَانَ الْأَنْعَامِ وَلَآمُرَنَّهُمْ فَلَيُغَيِّرُنَّ خَلْقَ اللَّهِ ۚ وَمَن يَتَّخِذِ الشَّيْطَانَ وَلِيًّا مِّن دُونِ اللَّهِ فَقَدْ خَسِرَ خُسْرَانًا مُّبِينًا
Dajudaju mo maa si won lona. Mo maa fi erokero sinu okan won. Mo maa pa won lase, won yo si maa ge eti eran-osin (lati ya a soto fun orisa). Mo maa pa won lase, won yo si maa yi eda Allahu pada." Enikeni ti o ba mu Esu ni ore leyin Allahu, dajudaju o ti sofo ni ofo ponnbele
120يَعِدُهُمْ وَيُمَنِّيهِمْ ۖ وَمَا يَعِدُهُمُ الشَّيْطَانُ إِلَّا غُرُورًا
Esu n sadehun fun won, o si n fi ife-iro sinu okan won. Esu ko si sadehun kan fun won bi ko se etan
121أُولَٰئِكَ مَأْوَاهُمْ جَهَنَّمُ وَلَا يَجِدُونَ عَنْهَا مَحِيصًا
Awon wonyen, ina Jahanamo ni ibugbe won; won ko si nii ri ibusasi kan
122وَالَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ سَنُدْخِلُهُمْ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا أَبَدًا ۖ وَعْدَ اللَّهِ حَقًّا ۚ وَمَنْ أَصْدَقُ مِنَ اللَّهِ قِيلًا
Awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si sise rere, A maa mu won wo inu awon Ogba Idera kan, ti odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re titi laelae. (O je) adehun ti Allahu se ni ti ododo. Ta si ni o so ododo ju Allahu lo
An-NisaAtokọ Kurani
176Ẹsẹ
MedinanRevelation
120Ẹsẹ
Itumọ — An-Nisa 120
Surah An-Nisa Ẹsẹ 120 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Esu n sadehun fun won, o si n fi ife-iro…Surah Ẹsẹ 120/176 — An-Nisa النساء (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Nisa Gbọ, An-Nisa Itumọ, An-Nisa mp3, An-Nisa pdf. Ẹsẹ 118–122. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








