An-Nisa · 20/176
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah An-Nisa
وَإِنْ أَرَدتُّمُ اسْتِبْدَالَ زَوْجٍ مَّكَانَ زَوْجٍ وَآتَيْتُمْ إِحْدَاهُنَّ قِنطَارًا فَلَا تَأْخُذُوا مِنْهُ شَيْئًا ۚ أَتَأْخُذُونَهُ بُهْتَانًا وَإِثْمًا مُّبِينًا ۝٢٠
Wa in arattumustib daala zawjim makaana zawjin wa aataitum ihdaahunna qintaaran falaa taakhuzoo minhu shai`aa; ataakhuzoonahoo buhtaannanw wa ismam mubeenaa
📖 Ni Yorùbá
Ti e ba si fe fi iyawo kan paaro aye iyawo kan, ti e si ti fun okan ninu won ni opolopo dukia, e o gbodo gba nnkan kan ninu re mo. Se eyin yoo gba a ni ti adapa iro (ti e n pa mo won) ati ese to foju han (ti e n da nipa won)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 18-22 — Surah An-Nisa

18وَلَيْسَتِ التَّوْبَةُ لِلَّذِينَ يَعْمَلُونَ السَّيِّئَاتِ حَتَّىٰ إِذَا حَضَرَ أَحَدَهُمُ الْمَوْتُ قَالَ إِنِّي تُبْتُ الْآنَ وَلَا الَّذِينَ يَمُوتُونَ وَهُمْ كُفَّارٌ ۚ أُولَٰئِكَ أَعْتَدْنَا لَهُمْ عَذَابًا أَلِيمًا
Ko si ironupiwada fun awon t’o n se aburu titi iku fi de ba okan ninu won, ki o wa wi pe: “Dajudaju emi ronu piwada nisinsin yii.” (Ko tun si ironupiwada) fun awon t’o ku sipo alaigbagbo. Awon wonyen, A ti pese iya eleta elero sile de won
19يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا لَا يَحِلُّ لَكُمْ أَن تَرِثُوا النِّسَاءَ كَرْهًا ۖ وَلَا تَعْضُلُوهُنَّ لِتَذْهَبُوا بِبَعْضِ مَا آتَيْتُمُوهُنَّ إِلَّا أَن يَأْتِينَ بِفَاحِشَةٍ مُّبَيِّنَةٍ ۚ وَعَاشِرُوهُنَّ بِالْمَعْرُوفِ ۚ فَإِن كَرِهْتُمُوهُنَّ فَعَسَىٰ أَن تَكْرَهُوا شَيْئًا وَيَجْعَلَ اللَّهُ فِيهِ خَيْرًا كَثِيرًا
Eyin ti e gbagbo ni ododo, ko letoo fun yin lati je awon obinrin mogun pelu ipa (bii sisu obinrin lopo.) E ma si di won lowo lati ko apa kan nnkan ti e fun won lo ayafi ti won ba huwa ibaje ponnbele. E ba won lopo pelu daadaa. Ti e ba korira won, o le je pe e korira kini kan, ki Allahu si ti fi opolopo oore sinu re
20وَإِنْ أَرَدتُّمُ اسْتِبْدَالَ زَوْجٍ مَّكَانَ زَوْجٍ وَآتَيْتُمْ إِحْدَاهُنَّ قِنطَارًا فَلَا تَأْخُذُوا مِنْهُ شَيْئًا ۚ أَتَأْخُذُونَهُ بُهْتَانًا وَإِثْمًا مُّبِينًا
Ti e ba si fe fi iyawo kan paaro aye iyawo kan, ti e si ti fun okan ninu won ni opolopo dukia, e o gbodo gba nnkan kan ninu re mo. Se eyin yoo gba a ni ti adapa iro (ti e n pa mo won) ati ese to foju han (ti e n da nipa won)
21وَكَيْفَ تَأْخُذُونَهُ وَقَدْ أَفْضَىٰ بَعْضُكُمْ إِلَىٰ بَعْضٍ وَأَخَذْنَ مِنكُم مِّيثَاقًا غَلِيظًا
Bawo ni eyin se le gba a pada nigba ti o je pe e ti wole to’ra yin, ti won si ti gba adehun t’o nipon lowo yin
22وَلَا تَنكِحُوا مَا نَكَحَ آبَاؤُكُم مِّنَ النِّسَاءِ إِلَّا مَا قَدْ سَلَفَ ۚ إِنَّهُ كَانَ فَاحِشَةً وَمَقْتًا وَسَاءَ سَبِيلًا
E ma se fe eni ti awon baba yin ti fe ninu awon obinrin ayafi eyi ti o ti re koja. Dajudaju o je iwa ibaje ati ohun ikorira. O si buru ni ona
An-NisaAtokọ Kurani
176Ẹsẹ
MedinanRevelation
20Ẹsẹ

Itumọ — An-Nisa 20

Surah An-Nisa Ẹsẹ 20 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti e ba si fe fi iyawo kan paaro aye…

Surah Ẹsẹ 20/176 — Surah An-Nisa النساء (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah An-Nisa Gbọ, Surah An-Nisa Itumọ, Surah An-Nisa mp3, Surah An-Nisa pdf. Ẹsẹ 18–22. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers