Al-A'raf · 63/206
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-A'raf
أَوَعَجِبْتُمْ أَن جَاءَكُمْ ذِكْرٌ مِّن رَّبِّكُمْ عَلَىٰ رَجُلٍ مِّنكُمْ لِيُنذِرَكُمْ وَلِتَتَّقُوا وَلَعَلَّكُمْ تُرْحَمُونَ ۝٦٣
awa`ajibtum an jaaa`akum zikrum mir Rabbikum `alaa rajulim minkum liyunzirakum wa litattaqoo wa la`allakum turhamoon
📖 Ni Yorùbá
Ati pe se e seemo pe iranti lati odo Oluwa yin de ba yin ni, (eyi ti Won fun) okunrin kan ninu yin nitori ki o le kilo fun yin; nitori ki e le beru (Allahu) ati nitori ki A le ke yin

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 61-65 — Surah Al-A'raf

61قَالَ يَا قَوْمِ لَيْسَ بِي ضَلَالَةٌ وَلَٰكِنِّي رَسُولٌ مِّن رَّبِّ الْعَالَمِينَ
O so pe: "Eyin ijo mi, ko si isina kan lodo mi, sugbon dajudaju emi ni Ojise kan lati odo Oluwa gbogbo eda
62أُبَلِّغُكُمْ رِسَالَاتِ رَبِّي وَأَنصَحُ لَكُمْ وَأَعْلَمُ مِنَ اللَّهِ مَا لَا تَعْلَمُونَ
Mo n je awon ise Oluwa mi fun yin. Mo n fun yin ni imoran rere. Ati pe ohun ti e o mo ni emi mo lati odo Allahu
63أَوَعَجِبْتُمْ أَن جَاءَكُمْ ذِكْرٌ مِّن رَّبِّكُمْ عَلَىٰ رَجُلٍ مِّنكُمْ لِيُنذِرَكُمْ وَلِتَتَّقُوا وَلَعَلَّكُمْ تُرْحَمُونَ
Ati pe se e seemo pe iranti lati odo Oluwa yin de ba yin ni, (eyi ti Won fun) okunrin kan ninu yin nitori ki o le kilo fun yin; nitori ki e le beru (Allahu) ati nitori ki A le ke yin
64فَكَذَّبُوهُ فَأَنجَيْنَاهُ وَالَّذِينَ مَعَهُ فِي الْفُلْكِ وَأَغْرَقْنَا الَّذِينَ كَذَّبُوا بِآيَاتِنَا ۚ إِنَّهُمْ كَانُوا قَوْمًا عَمِينَ
Won si pe e lopuro. Nitori naa, A gba oun ati awon t’o wa pelu re la ninu oko oju-omi. A si te awon t’o pe awon ayah Wa niro ri. Dajudaju won je ijo t’o foju (si ododo)
65۞ وَإِلَىٰ عَادٍ أَخَاهُمْ هُودًا ۗ قَالَ يَا قَوْمِ اعْبُدُوا اللَّهَ مَا لَكُم مِّنْ إِلَٰهٍ غَيْرُهُ ۚ أَفَلَا تَتَّقُونَ
A tun ran (eni kan) si awon ara ‘Ad, arakunrin won, Hud. O so pe: “Eyin ijo mi, e josin fun Allahu. E o ni olohun miiran leyin Re. Se e o nii beru (Re) ni
Al-A'rafAtokọ Kurani
206Ẹsẹ
MeccanRevelation
63Ẹsẹ

Itumọ — Al-A'raf 63

Surah Al-A'raf Ẹsẹ 63 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati pe se e seemo pe iranti lati odo Oluwa…

Surah Ẹsẹ 63/206 — Surah Al-A'raf الأعراف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-A'raf Gbọ, Surah Al-A'raf Itumọ, Surah Al-A'raf mp3, Surah Al-A'raf pdf. Ẹsẹ 61–65. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers