Taha · 134/135
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Taha
وَلَوْ أَنَّا أَهْلَكْنَاهُم بِعَذَابٍ مِّن قَبْلِهِ لَقَالُوا رَبَّنَا لَوْلَا أَرْسَلْتَ إِلَيْنَا رَسُولًا فَنَتَّبِعَ آيَاتِكَ مِن قَبْلِ أَن نَّذِلَّ وَنَخْزَىٰ ۝١٣٤
Wa law annaaa ahlaknaahum bi`azaabim min qablihee laqaaloo Rabbanaa law laaa arsalta ilainaa Rasoolan fanattabi`s Aayaatika min qabli an nazilla wa nakhzaa
📖 Ni Yorùbá
Ti o ba je pe dajudaju A ti fi iya kan pa won run siwaju re ni, won iba wi pe: "Oluwa wa nitori ki ni O o se ran Ojise kan si wa, awa iba tele awon ayah Re siwaju ki a to yepere, (ki a si to) kabuku

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 132-135 — Surah Taha

132وَأْمُرْ أَهْلَكَ بِالصَّلَاةِ وَاصْطَبِرْ عَلَيْهَا ۖ لَا نَسْأَلُكَ رِزْقًا ۖ نَّحْنُ نَرْزُقُكَ ۗ وَالْعَاقِبَةُ لِلتَّقْوَىٰ
Pa ara ile re lase irun kiki, ki o si se suuru lori re. A o nii beere ese kan lowo re; Awa l’A n pese fun o. Igbeyin rere si wa fun iberu (Allahu)
133وَقَالُوا لَوْلَا يَأْتِينَا بِآيَةٍ مِّن رَّبِّهِ ۚ أَوَلَمْ تَأْتِهِم بَيِّنَةُ مَا فِي الصُّحُفِ الْأُولَىٰ
Won wi pe: “Nitori ki ni ko fi mu ami kan wa fun wa lati odo Oluwa re?” Se eri t’o yanju t’o wa ninu awon takada akoko ko de ba won ni
134وَلَوْ أَنَّا أَهْلَكْنَاهُم بِعَذَابٍ مِّن قَبْلِهِ لَقَالُوا رَبَّنَا لَوْلَا أَرْسَلْتَ إِلَيْنَا رَسُولًا فَنَتَّبِعَ آيَاتِكَ مِن قَبْلِ أَن نَّذِلَّ وَنَخْزَىٰ
Ti o ba je pe dajudaju A ti fi iya kan pa won run siwaju re ni, won iba wi pe: "Oluwa wa nitori ki ni O o se ran Ojise kan si wa, awa iba tele awon ayah Re siwaju ki a to yepere, (ki a si to) kabuku
135قُلْ كُلٌّ مُّتَرَبِّصٌ فَتَرَبَّصُوا ۖ فَسَتَعْلَمُونَ مَنْ أَصْحَابُ الصِّرَاطِ السَّوِيِّ وَمَنِ اهْتَدَىٰ
So pe: “Eni kookan ni olureti (ikangun).” Nitori naa, e maa reti (re). E maa mo ta ni ero ona taara ati eni t’o mona
TahaAtokọ Kurani
135Ẹsẹ
MeccanRevelation
134Ẹsẹ

Itumọ — Taha 134

Surah Taha Ẹsẹ 134 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti o ba je pe dajudaju A ti fi iya…

Surah Ẹsẹ 134/135 — Surah Taha طه (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Taha Gbọ, Surah Taha Itumọ, Surah Taha mp3, Surah Taha pdf. Ẹsẹ 132–135. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers