Al-Furqan · 63/77
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Furqan
وَعِبَادُ الرَّحْمَٰنِ الَّذِينَ يَمْشُونَ عَلَى الْأَرْضِ هَوْنًا وَإِذَا خَاطَبَهُمُ الْجَاهِلُونَ قَالُوا سَلَامًا ۝٦٣
Wa `ibaadur Rahmaanil lazeena yamshoona `alal ardi hawnanw wa izaa khaata bahumul jaahiloona qaaloo salaamaa
📖 Ni Yorùbá
Awon erusin Ajoke-aye ni awon t’o n rin jeeje lori ile. Nigba ti awon ope ba si doju oro ko won, won yoo so oro alaafia

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 61-65 — Surah Al-Furqan

61تَبَارَكَ الَّذِي جَعَلَ فِي السَّمَاءِ بُرُوجًا وَجَعَلَ فِيهَا سِرَاجًا وَقَمَرًا مُّنِيرًا
Ibukun ni fun Eni ti O se awon irawo sinu sanmo. O tun se oorun ati osupa ni imole sinu re
62وَهُوَ الَّذِي جَعَلَ اللَّيْلَ وَالنَّهَارَ خِلْفَةً لِّمَنْ أَرَادَ أَن يَذَّكَّرَ أَوْ أَرَادَ شُكُورًا
Oun ni Eni ti O se oru ati osan ni itelentele (ti ikini yato si ikeji) nitori eni ti o ba gbero lati se iranti (Allahu) tabi ti o ba gbero idupe (fun Un)
63وَعِبَادُ الرَّحْمَٰنِ الَّذِينَ يَمْشُونَ عَلَى الْأَرْضِ هَوْنًا وَإِذَا خَاطَبَهُمُ الْجَاهِلُونَ قَالُوا سَلَامًا
Awon erusin Ajoke-aye ni awon t’o n rin jeeje lori ile. Nigba ti awon ope ba si doju oro ko won, won yoo so oro alaafia
64وَالَّذِينَ يَبِيتُونَ لِرَبِّهِمْ سُجَّدًا وَقِيَامًا
(Awon ni) awon t’o n lo oru won ni iforikanle ati iduro-kirun fun Oluwa won
65وَالَّذِينَ يَقُولُونَ رَبَّنَا اصْرِفْ عَنَّا عَذَابَ جَهَنَّمَ ۖ إِنَّ عَذَابَهَا كَانَ غَرَامًا
(Awon ni) awon t’o n so pe: “Oluwa wa, gbe iya ina Jahanamo kuro fun wa. Dajudaju iya re je iya ainipekun
Al-FurqanAtokọ Kurani
77Ẹsẹ
MeccanRevelation
63Ẹsẹ

Itumọ — Al-Furqan 63

Surah Al-Furqan Ẹsẹ 63 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon erusin Ajoke-aye ni awon t’o n rin jeeje lori…

Surah Ẹsẹ 63/77 — Surah Al-Furqan الفرقان (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Furqan Gbọ, Surah Al-Furqan Itumọ, Surah Al-Furqan mp3, Surah Al-Furqan pdf. Ẹsẹ 61–65. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers