Aal-Imran · 62/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Aal-Imran
إِنَّ هَٰذَا لَهُوَ الْقَصَصُ الْحَقُّ ۚ وَمَا مِنْ إِلَٰهٍ إِلَّا اللَّهُ ۚ وَإِنَّ اللَّهَ لَهُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ ۝٦٢
Innaa haazaa lahuwal qasasul haqq; wa maa min ilaahin illal laah; wa innal laahaa la Huwal `Azeezul Hakeem
📖 Ni Yorùbá
Dajudaju eyi, ohun ni itan ododo. Ati pe ko si olohun kan ti ijosin to si afi Allahu. Dajudaju Allahu, Oun ni Alagbara, Ologbon
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 60-64 — Aal-Imran

60الْحَقُّ مِن رَّبِّكَ فَلَا تَكُن مِّنَ الْمُمْتَرِينَ
Ododo ni lati odo Oluwa re. Nitori naa, ma se wa ninu awon oniyemeji
61فَمَنْ حَاجَّكَ فِيهِ مِن بَعْدِ مَا جَاءَكَ مِنَ الْعِلْمِ فَقُلْ تَعَالَوْا نَدْعُ أَبْنَاءَنَا وَأَبْنَاءَكُمْ وَنِسَاءَنَا وَنِسَاءَكُمْ وَأَنفُسَنَا وَأَنفُسَكُمْ ثُمَّ نَبْتَهِلْ فَنَجْعَل لَّعْنَتَ اللَّهِ عَلَى الْكَاذِبِينَ
Nitori naa, enikeni ti o ba ja o niyan nipa re leyin ohun ti o de ba o ninu imo, ki o so pe: “E wa! Ki a pe awon omokunrin wa ati awon omokunrin yin ati awon obinrin wa ati awon obinrin yin ati awa ati eyin naa. Leyin naa, ki a se adua taratara, ki a si toro egun Allahu le awon opuro lori.”
62إِنَّ هَٰذَا لَهُوَ الْقَصَصُ الْحَقُّ ۚ وَمَا مِنْ إِلَٰهٍ إِلَّا اللَّهُ ۚ وَإِنَّ اللَّهَ لَهُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Dajudaju eyi, ohun ni itan ododo. Ati pe ko si olohun kan ti ijosin to si afi Allahu. Dajudaju Allahu, Oun ni Alagbara, Ologbon
63فَإِن تَوَلَّوْا فَإِنَّ اللَّهَ عَلِيمٌ بِالْمُفْسِدِينَ
Ti won ba si peyin da (nibi ododo naa), dajudaju Allahu ni Onimo nipa awon obileje
64قُلْ يَا أَهْلَ الْكِتَابِ تَعَالَوْا إِلَىٰ كَلِمَةٍ سَوَاءٍ بَيْنَنَا وَبَيْنَكُمْ أَلَّا نَعْبُدَ إِلَّا اللَّهَ وَلَا نُشْرِكَ بِهِ شَيْئًا وَلَا يَتَّخِذَ بَعْضُنَا بَعْضًا أَرْبَابًا مِّن دُونِ اللَّهِ ۚ فَإِن تَوَلَّوْا فَقُولُوا اشْهَدُوا بِأَنَّا مُسْلِمُونَ
So pe: “Eyin ahlu-l-kitab, e wa sibi oro kan t’o dogba laaarin awa ati eyin, pe a o nii josin fun eni kan afi Allahu. A o si nii fi kini kan wa akegbe fun Un. Ati pe apa kan wa ko nii so apa kan di oluwa leyin Allahu.” Ti won ba si gbunri, e so pe: “E jerii pe dajudaju musulumi ni awa.”
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
62Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 62

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 62 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Dajudaju eyi, ohun ni itan ododo. Ati pe ko si…

Surah Ẹsẹ 62/200 — Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Aal-Imran Gbọ, Aal-Imran Itumọ, Aal-Imran mp3, Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 60–64. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers