An-Nisa · 67/176
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Nisa
وَإِذًا لَّآتَيْنَاهُم مِّن لَّدُنَّا أَجْرًا عَظِيمًا ٦٧
Transliteration
Wa izal la aatainaahum mil ladunnaaa ajran `azeemaa
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Nigba naa, dajudaju Awa iba fun won ni esan nla lati odo Wa
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 65-69 — An-Nisa
65فَلَا وَرَبِّكَ لَا يُؤْمِنُونَ حَتَّىٰ يُحَكِّمُوكَ فِيمَا شَجَرَ بَيْنَهُمْ ثُمَّ لَا يَجِدُوا فِي أَنفُسِهِمْ حَرَجًا مِّمَّا قَضَيْتَ وَيُسَلِّمُوا تَسْلِيمًا
Rara, Emi fi Oluwa re bura pe won ko ti i gbagbo ni ododo titi won yoo fi gba o ni oludajo lori ohun ti o ba da yanponyanrin sile laaarin won. Leyin naa, won ko nii ni ehonu kan si idajo ti o ba da. Won si maa gba patapata
66وَلَوْ أَنَّا كَتَبْنَا عَلَيْهِمْ أَنِ اقْتُلُوا أَنفُسَكُمْ أَوِ اخْرُجُوا مِن دِيَارِكُم مَّا فَعَلُوهُ إِلَّا قَلِيلٌ مِّنْهُمْ ۖ وَلَوْ أَنَّهُمْ فَعَلُوا مَا يُوعَظُونَ بِهِ لَكَانَ خَيْرًا لَّهُمْ وَأَشَدَّ تَثْبِيتًا
Ti o ba je pe A se e ni oran-anyan fun won pe: "E para yin tabi e jade kuro ninu ilu yin," won ko nii se e afi die ninu won. Ti o ba tun je pe won se ohun ti A fi n se waasi fun won ni, iba je oore ati idurosinsin to lagbara julo fun won
67وَإِذًا لَّآتَيْنَاهُم مِّن لَّدُنَّا أَجْرًا عَظِيمًا
Nigba naa, dajudaju Awa iba fun won ni esan nla lati odo Wa
68وَلَهَدَيْنَاهُمْ صِرَاطًا مُّسْتَقِيمًا
Ati pe dajudaju Awa iba to won si ona taara
69وَمَن يُطِعِ اللَّهَ وَالرَّسُولَ فَأُولَٰئِكَ مَعَ الَّذِينَ أَنْعَمَ اللَّهُ عَلَيْهِم مِّنَ النَّبِيِّينَ وَالصِّدِّيقِينَ وَالشُّهَدَاءِ وَالصَّالِحِينَ ۚ وَحَسُنَ أُولَٰئِكَ رَفِيقًا
Enikeni ti o ba tele (ase) Allahu ati (ase) Ojise naa, awon wonyen maa wa (ninu Ogba Idera) pelu awon ti Allahu sedera fun ninu awon Anabi, awon olododo, awon t’o ku s’oju ogun esin ati awon eni rere. Awon wonyen si dara ni alabaarin
An-NisaAtokọ Kurani
176Ẹsẹ
MedinanRevelation
67Ẹsẹ
Itumọ — An-Nisa 67
Surah An-Nisa Ẹsẹ 67 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Nigba naa, dajudaju Awa iba fun won ni esan nla…Surah Ẹsẹ 67/176 — An-Nisa النساء (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Nisa Gbọ, An-Nisa Itumọ, An-Nisa mp3, An-Nisa pdf. Ẹsẹ 65–69. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








