Ar-Rahman · 8/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Ar-Rahman
أَلَّا تَطْغَوْا فِي الْمِيزَانِ ۝٨
Allaa tatghaw fil meezaan
📖 Ni Yorùbá
pe ki e ma se tayo enu-ala nibi osuwon
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 6-10 — Ar-Rahman

6وَالنَّجْمُ وَالشَّجَرُ يَسْجُدَانِ
Awon itakun ile ati igi n fori kanle (fun Allahu)
7وَالسَّمَاءَ رَفَعَهَا وَوَضَعَ الْمِيزَانَ
Ati sanmo, Allahu gbe e soke. O si fi osuwon ofin deede lele (fun eda)
8أَلَّا تَطْغَوْا فِي الْمِيزَانِ
pe ki e ma se tayo enu-ala nibi osuwon
9وَأَقِيمُوا الْوَزْنَ بِالْقِسْطِ وَلَا تُخْسِرُوا الْمِيزَانَ
E gbe osuwon naa duro pelu dogbadogba. Ki e si ma se din osuwon ku
10وَالْأَرْضَ وَضَعَهَا لِلْأَنَامِ
Ile, (Allahu) te e sile fun awon eda
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
8Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 8

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 8 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : pe ki e ma se tayo enu-ala nibi osuwon

Surah Ẹsẹ 8/78 — Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Ar-Rahman Gbọ, Ar-Rahman Itumọ, Ar-Rahman mp3, Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 6–10. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers