Ar-Rahman · 7/78
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ar-Rahman
وَالسَّمَاءَ رَفَعَهَا وَوَضَعَ الْمِيزَانَ ۝٧
Wassamaaa`a rafa`ahaa wa wada`al Meezan
📖 Ni Yorùbá
Ati sanmo, Allahu gbe e soke. O si fi osuwon ofin deede lele (fun eda)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 5-9 — Surah Ar-Rahman

5الشَّمْسُ وَالْقَمَرُ بِحُسْبَانٍ
Oorun ati osupa (n rin) fun isiro (ojo aye)
6وَالنَّجْمُ وَالشَّجَرُ يَسْجُدَانِ
Awon itakun ile ati igi n fori kanle (fun Allahu)
7وَالسَّمَاءَ رَفَعَهَا وَوَضَعَ الْمِيزَانَ
Ati sanmo, Allahu gbe e soke. O si fi osuwon ofin deede lele (fun eda)
8أَلَّا تَطْغَوْا فِي الْمِيزَانِ
pe ki e ma se tayo enu-ala nibi osuwon
9وَأَقِيمُوا الْوَزْنَ بِالْقِسْطِ وَلَا تُخْسِرُوا الْمِيزَانَ
E gbe osuwon naa duro pelu dogbadogba. Ki e si ma se din osuwon ku
Ar-RahmanAtokọ Kurani
78Ẹsẹ
MedinanRevelation
7Ẹsẹ

Itumọ — Ar-Rahman 7

Surah Ar-Rahman Ẹsẹ 7 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ati sanmo, Allahu gbe e soke. O si fi osuwon…

Surah Ẹsẹ 7/78 — Surah Ar-Rahman الرحمن (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ar-Rahman Gbọ, Surah Ar-Rahman Itumọ, Surah Ar-Rahman mp3, Surah Ar-Rahman pdf. Ẹsẹ 5–9. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers