Al-An'am · 116/165
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-An'am
وَإِن تُطِعْ أَكْثَرَ مَن فِي الْأَرْضِ يُضِلُّوكَ عَن سَبِيلِ اللَّهِ ۚ إِن يَتَّبِعُونَ إِلَّا الظَّنَّ وَإِنْ هُمْ إِلَّا يَخْرُصُونَ ۝١١٦
Wa in tuti` aksara man fil ardi yudillooka `an sabeelil laah; iny yattabi`oona illaz zanna wa in hum illaa yakhrusoon
📖 Ni Yorùbá
Ti o ba tele opolopo awon ti n be lori ile, won maa si o lona kuro loju ona (esin) Allahu. Won ko tele kini kan bi ko se aroso. Ki si ni won (n se) bi ko se pe won n paro
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 114-118 — Al-An'am

114أَفَغَيْرَ اللَّهِ أَبْتَغِي حَكَمًا وَهُوَ الَّذِي أَنزَلَ إِلَيْكُمُ الْكِتَابَ مُفَصَّلًا ۚ وَالَّذِينَ آتَيْنَاهُمُ الْكِتَابَ يَعْلَمُونَ أَنَّهُ مُنَزَّلٌ مِّن رَّبِّكَ بِالْحَقِّ ۖ فَلَا تَكُونَنَّ مِنَ الْمُمْتَرِينَ
Se nnkan miiran ni ki ng wa ni oludajo leyin Allahu ni? Oun si ni Eni ti O so Tira kale fun yin ti won fi salaye idajo. Awon ti A si fun ni tira mo pe, dajudaju won so o kale pelu ododo lati odo Oluwa re. Nitori naa, o o gbodo wa lara awon oniyemeji
115وَتَمَّتْ كَلِمَتُ رَبِّكَ صِدْقًا وَعَدْلًا ۚ لَّا مُبَدِّلَ لِكَلِمَاتِهِ ۚ وَهُوَ السَّمِيعُ الْعَلِيمُ
Oro Oluwa re pe ni ododo ati ni deede. Ko si alayiipada kan fun awon oro Re. Oun si ni Olugbo, Onimo
116وَإِن تُطِعْ أَكْثَرَ مَن فِي الْأَرْضِ يُضِلُّوكَ عَن سَبِيلِ اللَّهِ ۚ إِن يَتَّبِعُونَ إِلَّا الظَّنَّ وَإِنْ هُمْ إِلَّا يَخْرُصُونَ
Ti o ba tele opolopo awon ti n be lori ile, won maa si o lona kuro loju ona (esin) Allahu. Won ko tele kini kan bi ko se aroso. Ki si ni won (n se) bi ko se pe won n paro
117إِنَّ رَبَّكَ هُوَ أَعْلَمُ مَن يَضِلُّ عَن سَبِيلِهِ ۖ وَهُوَ أَعْلَمُ بِالْمُهْتَدِينَ
Dajudaju Oluwa re, Oun l’O nimo julo nipa eni t’o sina loju ona (esin) Re. Ati pe, Oun si l’O nimo julo nipa awon olumona
118فَكُلُوا مِمَّا ذُكِرَ اسْمُ اللَّهِ عَلَيْهِ إِن كُنتُم بِآيَاتِهِ مُؤْمِنِينَ
Nitori naa, e je ninu ohun ti won ba fi oruko Allahu pa, ti e ba gbagbo ninu awon ayah Re
Al-An'amAtokọ Kurani
165Ẹsẹ
MeccanRevelation
116Ẹsẹ

Itumọ — Al-An'am 116

Surah Al-An'am Ẹsẹ 116 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti o ba tele opolopo awon ti n be lori…

Surah Ẹsẹ 116/165 — Al-An'am الأنعام (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-An'am Gbọ, Al-An'am Itumọ, Al-An'am mp3, Al-An'am pdf. Ẹsẹ 114–118. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers