Al-Qalam · 13/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
عُتُلٍّ بَعْدَ ذَٰلِكَ زَنِيمٍ ۝١٣
Utullim ba`da zaalika zaneem
📖 Ni Yorùbá
odaju. Leyin iyen, asawo ni

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 11-15 — Surah Al-Qalam

11هَمَّازٍ مَّشَّاءٍ بِنَمِيمٍ
abuni, alarinka t’o n sofofo kiri
12مَّنَّاعٍ لِّلْخَيْرِ مُعْتَدٍ أَثِيمٍ
oludena ise rere, alakoyo, elese
13عُتُلٍّ بَعْدَ ذَٰلِكَ زَنِيمٍ
odaju. Leyin iyen, asawo ni
14أَن كَانَ ذَا مَالٍ وَبَنِينَ
Nitori pe o ni dukia ati awon omokunrin
15إِذَا تُتْلَىٰ عَلَيْهِ آيَاتُنَا قَالَ أَسَاطِيرُ الْأَوَّلِينَ
nigba ti won ba n ke awon ayah Wa fun un, o maa wi pe: “Akosile alo awon eni akoko (niwonyi)”
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
13Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 13

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 13 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : odaju. Leyin iyen, asawo ni

Surah Ẹsẹ 13/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 11–15. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers