Al-Qalam · 16/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
سَنَسِمُهُ عَلَى الْخُرْطُومِ ۝١٦
Sanasimuhoo `alal khurtoom
📖 Ni Yorùbá
A maa fi ami si i ni gongori imu

M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
0:00
0:00


📜 Ẹsẹ 14-18 — Surah Al-Qalam

14أَن كَانَ ذَا مَالٍ وَبَنِينَ
Nitori pe o ni dukia ati awon omokunrin
15إِذَا تُتْلَىٰ عَلَيْهِ آيَاتُنَا قَالَ أَسَاطِيرُ الْأَوَّلِينَ
nigba ti won ba n ke awon ayah Wa fun un, o maa wi pe: “Akosile alo awon eni akoko (niwonyi)”
16سَنَسِمُهُ عَلَى الْخُرْطُومِ
A maa fi ami si i ni gongori imu
17إِنَّا بَلَوْنَاهُمْ كَمَا بَلَوْنَا أَصْحَابَ الْجَنَّةِ إِذْ أَقْسَمُوا لَيَصْرِمُنَّهَا مُصْبِحِينَ
Dajudaju Awa dan won wo gege bi A se dan awon ologba wo nigba ti won bura pe dajudaju awon yoo ka gbogbo eso ogba naa ni owuro kutukutu
18وَلَا يَسْتَثْنُونَ
Won ko si se ayafi pe "ti Allahu ba fe
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
16Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 16

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 16 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : A maa fi ami si i ni gongori imu

Surah Ẹsẹ 16/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 14–18. Ni Yorùbá: العربية.





Al-Kur'an


Tuesday, September 29, 2026

Don't forget us in your sincere prayers