Al-Qalam · 21/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
فَتَنَادَوْا مُصْبِحِينَ ۝٢١
Fatanaadaw musbiheen
📖 Ni Yorùbá
Won n pera won ni owuro kutukutu

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 19-23 — Surah Al-Qalam

19فَطَافَ عَلَيْهَا طَائِفٌ مِّن رَّبِّكَ وَهُمْ نَائِمُونَ
Adanwo t’o n yi nnkan po lati odo Oluwa re si yi ogba naa po, nigba ti won sun lo
20فَأَصْبَحَتْ كَالصَّرِيمِ
O si da bi oko agedanu (ti won ti resun)
21فَتَنَادَوْا مُصْبِحِينَ
Won n pera won ni owuro kutukutu
22أَنِ اغْدُوا عَلَىٰ حَرْثِكُمْ إِن كُنتُمْ صَارِمِينَ
pe e ji lo si oko yin ti e ba fe ka eso
23فَانطَلَقُوا وَهُمْ يَتَخَافَتُونَ
Won lo, won si n fi ohun jeeje bara won soro
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
21Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 21

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 21 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Won n pera won ni owuro kutukutu

Surah Ẹsẹ 21/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 19–23. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers