Al-Ma'arij · 31/44
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Ma'arij
فَمَنِ ابْتَغَىٰ وَرَاءَ ذَٰلِكَ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْعَادُونَ ۝٣١
Famanib taghaa waraaa`a zaalika fa ulaaa`ika humul `aadoon
📖 Ni Yorùbá
nitori naa, eni keni t’o ba n wa nnkan miiran leyin iyen, awon wonyen ni awon olutayo-enu ala

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 29-33 — Surah Al-Ma'arij

29وَالَّذِينَ هُمْ لِفُرُوجِهِمْ حَافِظُونَ
awon t’o n so abe won
30إِلَّا عَلَىٰ أَزْوَاجِهِمْ أَوْ مَا مَلَكَتْ أَيْمَانُهُمْ فَإِنَّهُمْ غَيْرُ مَلُومِينَ
ayafi lodo awon iyawo won tabi erubinrin won ni won ko ti le je eni-eebu
31فَمَنِ ابْتَغَىٰ وَرَاءَ ذَٰلِكَ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْعَادُونَ
nitori naa, eni keni t’o ba n wa nnkan miiran leyin iyen, awon wonyen ni awon olutayo-enu ala
32وَالَّذِينَ هُمْ لِأَمَانَاتِهِمْ وَعَهْدِهِمْ رَاعُونَ
awon t’o n so agbafipamo won ati adehun won
33وَالَّذِينَ هُم بِشَهَادَاتِهِمْ قَائِمُونَ
awon t’o n duro ti ijerii won
Al-Ma'arijAtokọ Kurani
44Ẹsẹ
MeccanRevelation
31Ẹsẹ

Itumọ — Al-Ma'arij 31

Surah Al-Ma'arij Ẹsẹ 31 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : nitori naa, eni keni t’o ba n wa nnkan miiran…

Surah Ẹsẹ 31/44 — Surah Al-Ma'arij المعارج (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Ma'arij Gbọ, Surah Al-Ma'arij Itumọ, Surah Al-Ma'arij mp3, Surah Al-Ma'arij pdf. Ẹsẹ 29–33. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers