Al-Mu'minun · 91/118
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Mu'minun
مَا اتَّخَذَ اللَّهُ مِن وَلَدٍ وَمَا كَانَ مَعَهُ مِنْ إِلَٰهٍ ۚ إِذًا لَّذَهَبَ كُلُّ إِلَٰهٍ بِمَا خَلَقَ وَلَعَلَا بَعْضُهُمْ عَلَىٰ بَعْضٍ ۚ سُبْحَانَ اللَّهِ عَمَّا يَصِفُونَ ۝٩١
Mat takhazal laahu minw waladinw wa maa kaana ma`ahoo min ilaah; izal lazahaba kullu ilaahim bimaa khalaqa wa la`alaa ba`duhum `alaa ba`d; Subhaannal laahi `ammaa yasifoon
📖 Ni Yorùbá
Allahu ko fi eni kan kan se omo, ko si si olohun kan pelu Re. (Ti ko ba ri bee) nigba naa, olohun kookan iba ti ko eda t’o da lo, apa kan won iba si bori apa kan. Mimo ni fun Allahu tayo ohun ti won n fi royin (Re nipa omo bibi)

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 89-93 — Surah Al-Mu'minun

89سَيَقُولُونَ لِلَّهِ ۚ قُلْ فَأَنَّىٰ تُسْحَرُونَ
Won a wi pe: “Ti Allahu ni.” So pe: “Nitori naa, bawo ni won se n dan yin?”
90بَلْ أَتَيْنَاهُم بِالْحَقِّ وَإِنَّهُمْ لَكَاذِبُونَ
Amo sa, ododo ni A mu wa ba won. Dajudaju awon si ni opuro
91مَا اتَّخَذَ اللَّهُ مِن وَلَدٍ وَمَا كَانَ مَعَهُ مِنْ إِلَٰهٍ ۚ إِذًا لَّذَهَبَ كُلُّ إِلَٰهٍ بِمَا خَلَقَ وَلَعَلَا بَعْضُهُمْ عَلَىٰ بَعْضٍ ۚ سُبْحَانَ اللَّهِ عَمَّا يَصِفُونَ
Allahu ko fi eni kan kan se omo, ko si si olohun kan pelu Re. (Ti ko ba ri bee) nigba naa, olohun kookan iba ti ko eda t’o da lo, apa kan won iba si bori apa kan. Mimo ni fun Allahu tayo ohun ti won n fi royin (Re nipa omo bibi)
92عَالِمِ الْغَيْبِ وَالشَّهَادَةِ فَتَعَالَىٰ عَمَّا يُشْرِكُونَ
(Allahu) Onimo-ikoko ati gbangba. Nitori naa, O ga tayo nnkan ti won fi n sebo si I
93قُل رَّبِّ إِمَّا تُرِيَنِّي مَا يُوعَدُونَ
So pe: “Oluwa mi, O see se ki O fi ohun ti won n se ni adehun fun won han mi
Al-Mu'minunAtokọ Kurani
118Ẹsẹ
MeccanRevelation
91Ẹsẹ

Itumọ — Al-Mu'minun 91

Surah Al-Mu'minun Ẹsẹ 91 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Allahu ko fi eni kan kan se omo, ko si…

Surah Ẹsẹ 91/118 — Surah Al-Mu'minun المؤمنون (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Mu'minun Gbọ, Surah Al-Mu'minun Itumọ, Surah Al-Mu'minun mp3, Surah Al-Mu'minun pdf. Ẹsẹ 89–93. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers