An-Naml · 67/93
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah An-Naml
وَقَالَ الَّذِينَ كَفَرُوا أَإِذَا كُنَّا تُرَابًا وَآبَاؤُنَا أَئِنَّا لَمُخْرَجُونَ ۝٦٧
Wa qaalal lazeena kafarooo `a-izaa kunnaa turaabanw wa aabaaa`unaaa a`innaa lamukhrajoon
📖 Ni Yorùbá
Awon t’o sai gbagbo wi pe: “Se nigba ti awa ati awon baba wa ba ti di erupe, se (nigba naa ni) won yoo mu wa jade

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 65-69 — Surah An-Naml

65قُل لَّا يَعْلَمُ مَن فِي السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ الْغَيْبَ إِلَّا اللَّهُ ۚ وَمَا يَشْعُرُونَ أَيَّانَ يُبْعَثُونَ
So pe: “Awon t’o wa ninu awon sanmo ati ile ko nimo ikoko afi Allahu. Ati pe won ko si mo asiko wo ni A maa gbe awon oku dide.”
66بَلِ ادَّارَكَ عِلْمُهُمْ فِي الْآخِرَةِ ۚ بَلْ هُمْ فِي شَكٍّ مِّنْهَا ۖ بَلْ هُم مِّنْهَا عَمُونَ
Bee ni, ni orun ni imo won maa to mo Ojo Ikeyin (loran). Bee ni, won wa ninu iyemeji nipa re (bayii). Bee ni, won ti fonu-fora nipa re
67وَقَالَ الَّذِينَ كَفَرُوا أَإِذَا كُنَّا تُرَابًا وَآبَاؤُنَا أَئِنَّا لَمُخْرَجُونَ
Awon t’o sai gbagbo wi pe: “Se nigba ti awa ati awon baba wa ba ti di erupe, se (nigba naa ni) won yoo mu wa jade
68لَقَدْ وُعِدْنَا هَٰذَا نَحْنُ وَآبَاؤُنَا مِن قَبْلُ إِنْ هَٰذَا إِلَّا أَسَاطِيرُ الْأَوَّلِينَ
Won kuku ti se adehun eyi fun awa ati awon baba wa teletele. Eyi ko je kini kan bi ko se akosile alo awon eni akoko.”
69قُلْ سِيرُوا فِي الْأَرْضِ فَانظُرُوا كَيْفَ كَانَ عَاقِبَةُ الْمُجْرِمِينَ
So pe: “E rin kiri lori ile, ki e wo bi atubotan awon elese se ri.”
An-NamlAtokọ Kurani
93Ẹsẹ
MeccanRevelation
67Ẹsẹ

Itumọ — An-Naml 67

Surah An-Naml Ẹsẹ 67 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Awon t’o sai gbagbo wi pe: “Se nigba ti awa…

Surah Ẹsẹ 67/93 — Surah An-Naml النمل (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah An-Naml Gbọ, Surah An-Naml Itumọ, Surah An-Naml mp3, Surah An-Naml pdf. Ẹsẹ 65–69. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers