Aal-Imran · 6/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
هُوَ الَّذِي يُصَوِّرُكُمْ فِي الْأَرْحَامِ كَيْفَ يَشَاءُ ۚ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ ۝٦
Huwal lazee yusawwirukum fil arhaami kaifa yashaaa`; laa ilaaha illaa Huwal `Azeezul Hakeem
📖 Ni Yorùbá
Oun ni Eni ti O n yaworan yin sinu apoluke bi O se fe. Ko si olohun kan ti ijosin to si afi Oun, Alagbara Ologbon

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 4-8 — Surah Aal-Imran

4مِن قَبْلُ هُدًى لِّلنَّاسِ وَأَنزَلَ الْفُرْقَانَ ۗ إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا بِآيَاتِ اللَّهِ لَهُمْ عَذَابٌ شَدِيدٌ ۗ وَاللَّهُ عَزِيزٌ ذُو انتِقَامٍ
ni isaaju. Imona si ni fun awon eniyan.1 O tun so oro-ipinya (oro t’o n sepinya laaarin ododo ati iro) kale.2 Dajudaju awon t’o sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, iya t’o le n be fun won. Allahu si ni Alagbara, Olugbesan
5إِنَّ اللَّهَ لَا يَخْفَىٰ عَلَيْهِ شَيْءٌ فِي الْأَرْضِ وَلَا فِي السَّمَاءِ
Dajudaju Allahu, ko si kini kan t’o pamo fun Un ninu ile ati ninu sanmo
6هُوَ الَّذِي يُصَوِّرُكُمْ فِي الْأَرْحَامِ كَيْفَ يَشَاءُ ۚ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Oun ni Eni ti O n yaworan yin sinu apoluke bi O se fe. Ko si olohun kan ti ijosin to si afi Oun, Alagbara Ologbon
7هُوَ الَّذِي أَنزَلَ عَلَيْكَ الْكِتَابَ مِنْهُ آيَاتٌ مُّحْكَمَاتٌ هُنَّ أُمُّ الْكِتَابِ وَأُخَرُ مُتَشَابِهَاتٌ ۖ فَأَمَّا الَّذِينَ فِي قُلُوبِهِمْ زَيْغٌ فَيَتَّبِعُونَ مَا تَشَابَهَ مِنْهُ ابْتِغَاءَ الْفِتْنَةِ وَابْتِغَاءَ تَأْوِيلِهِ ۗ وَمَا يَعْلَمُ تَأْوِيلَهُ إِلَّا اللَّهُ ۗ وَالرَّاسِخُونَ فِي الْعِلْمِ يَقُولُونَ آمَنَّا بِهِ كُلٌّ مِّنْ عِندِ رَبِّنَا ۗ وَمَا يَذَّكَّرُ إِلَّا أُولُو الْأَلْبَابِ
Oun ni Eni ti O so Tira kale fun o; awon ayah alainipon-na wa ninu re - awon si ni ipile Tira -, onipon-na si ni iyoku. Ni ti awon ti igbunri kuro nibi ododo wa ninu okan won, won yoo maa tele eyi t’o ni pon-na ninu re lati fi wa wahala ati lati fi wa itumo (odi) fun un. Ko si si eni t’o nimo itumo re afi Allahu. Awon agba ninu imo esin, won n so pe: “A gba a gbo. Lati odo Oluwa wa ni gbogbo re (ti sokale).” Ko si eni t’o n lo iranti ayafi awon onilaakaye. ko si ayah tabi hadith kan ti o ni pon-na ti itakora won wa wo ipo “itakora toribee” (at-ta‘arudu al-haƙiƙiy). Eyi wa ni ibamu si surah an-Nisa’
8رَبَّنَا لَا تُزِغْ قُلُوبَنَا بَعْدَ إِذْ هَدَيْتَنَا وَهَبْ لَنَا مِن لَّدُنكَ رَحْمَةً ۚ إِنَّكَ أَنتَ الْوَهَّابُ
Oluwa wa, ma se yi wa lokan pada leyin ti O ti to wa sona. Ta wa lore ike lati odo Re, dajudaju Iwo ni Olore
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
6Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 6

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 6 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Oun ni Eni ti O n yaworan yin sinu apoluke…

Surah Ẹsẹ 6/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 4–8. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers