As-Saffat · 124/182
Itumọ Aṣẹ ohun — As-Saffat
إِذْ قَالَ لِقَوْمِهِ أَلَا تَتَّقُونَ ۝١٢٤
Iz qaala liqawmiheee alaa tattaqoon
📖 Ni Yorùbá
(E ranti) nigba ti o so fun ijo re pe: "Se e o nii beru Allahu ni
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 122-126 — As-Saffat

122إِنَّهُمَا مِنْ عِبَادِنَا الْمُؤْمِنِينَ
Dajudaju awon mejeeji wa ninu awon erusin Wa, awon onigbagbo ododo
123وَإِنَّ إِلْيَاسَ لَمِنَ الْمُرْسَلِينَ
Dajudaju (Anabi) ’Ilyas wa ninu awon Ojise
124إِذْ قَالَ لِقَوْمِهِ أَلَا تَتَّقُونَ
(E ranti) nigba ti o so fun ijo re pe: "Se e o nii beru Allahu ni
125أَتَدْعُونَ بَعْلًا وَتَذَرُونَ أَحْسَنَ الْخَالِقِينَ
Se e oo maa pe orisa kan, e si maa fi Eni t’O dara julo ninu awon eledaa sile, وَهُوَ خَيْرُ ٱلْحَٰكِمِينَ Oun l’O si dara julo ninu awon oludajo. (surah al-’A‘rof 7:87) وَهُوَ أَسْرَعُ ٱلْحَٰسِبِينَ Oun si yara julo ninu awon onisiro. (surah al-’Ani‘am 6:62) oludajo alaaanu ibaa mo bii omo ina igun afi ki Allahu je Eledaa re. Koda adamo owo ati okowo ti won so di “oro-Aje. Awon t’o n bo elomiiran naa n sora won di olupese. Yato si pe Allahu ti fi rinle pe Oun nikan ni Olupese fun gbogbo eda Re. Ti eyi ko ba ti i da awon kan loju bee ti won si fe gbe gbogbo ipese olukuluku lori iwon ninu aanu ti Allahu fi si awon eda kan lokan ni won fi di alaaanu. Nitori naa Allahu ni Alaaanu julo ninu awon alaaanu
126اللَّهَ رَبَّكُمْ وَرَبَّ آبَائِكُمُ الْأَوَّلِينَ
(e n fi) Allahu (sile), Oluwa yin ati Oluwa awon baba yin, awon eni akoko
As-SaffatAtokọ Kurani
182Ẹsẹ
MeccanRevelation
124Ẹsẹ

Itumọ — As-Saffat 124

Surah As-Saffat Ẹsẹ 124 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : (E ranti) nigba ti o so fun ijo re pe:…

Surah Ẹsẹ 124/182 — As-Saffat الصافات (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: As-Saffat Gbọ, As-Saffat Itumọ, As-Saffat mp3, As-Saffat pdf. Ẹsẹ 122–126. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers