An-Nisa · 109/176
Itumọ Aṣẹ ohun — An-Nisa
هَا أَنتُمْ هَٰؤُلَاءِ جَادَلْتُمْ عَنْهُمْ فِي الْحَيَاةِ الدُّنْيَا فَمَن يُجَادِلُ اللَّهَ عَنْهُمْ يَوْمَ الْقِيَامَةِ أَم مَّن يَكُونُ عَلَيْهِمْ وَكِيلًا ۝١٠٩
haaa antum haaa`ulaaa`i jaadaltum `anhum fil hayaatid dunyaa famai yujaadilul laaha `anhum Yawmal Qiyaamati am mai yakoonu `alaihim wakeelaa
📖 Ni Yorùbá
Kiye si i, eyin wonyi ni e n ba won mu awijare wa nile aye. Ta ni o maa ba won mu awijare wa ni odo Allahu ni Ojo Ajinde? Tabi ta ni o maa je alaabo fun won
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 107-111 — An-Nisa

107وَلَا تُجَادِلْ عَنِ الَّذِينَ يَخْتَانُونَ أَنفُسَهُمْ ۚ إِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ مَن كَانَ خَوَّانًا أَثِيمًا
Ma se ba awon t’o n janba emi ara won wa awijare. Dajudaju Allahu ko feran enikeni ti o je onijanba, elese
108يَسْتَخْفُونَ مِنَ النَّاسِ وَلَا يَسْتَخْفُونَ مِنَ اللَّهِ وَهُوَ مَعَهُمْ إِذْ يُبَيِّتُونَ مَا لَا يَرْضَىٰ مِنَ الْقَوْلِ ۚ وَكَانَ اللَّهُ بِمَا يَعْمَلُونَ مُحِيطًا
Won n fi ara pamo fun awon eniyan, won ko si le fara pamo fun Allahu (nitori pe) O wa pelu won (pelu imo Re) nigba ti won n gbimo ohun ti (Allahu) ko yonu si ninu oro siso. Allahu si n je Alamotan nipa ohun ti won n se nise
109هَا أَنتُمْ هَٰؤُلَاءِ جَادَلْتُمْ عَنْهُمْ فِي الْحَيَاةِ الدُّنْيَا فَمَن يُجَادِلُ اللَّهَ عَنْهُمْ يَوْمَ الْقِيَامَةِ أَم مَّن يَكُونُ عَلَيْهِمْ وَكِيلًا
Kiye si i, eyin wonyi ni e n ba won mu awijare wa nile aye. Ta ni o maa ba won mu awijare wa ni odo Allahu ni Ojo Ajinde? Tabi ta ni o maa je alaabo fun won
110وَمَن يَعْمَلْ سُوءًا أَوْ يَظْلِمْ نَفْسَهُ ثُمَّ يَسْتَغْفِرِ اللَّهَ يَجِدِ اللَّهَ غَفُورًا رَّحِيمًا
Enikeni ti o ba sise aburu kan tabi ti o sabosi si emi ara re, leyin naa ti o toro aforijin lodo Allahu, o maa ba Allahu ni Alaforijin, Alaaanu
111وَمَن يَكْسِبْ إِثْمًا فَإِنَّمَا يَكْسِبُهُ عَلَىٰ نَفْسِهِ ۚ وَكَانَ اللَّهُ عَلِيمًا حَكِيمًا
Enikeni ti o ba da ese kan, o da a fun emi ara re. Allahu si n je Onimo, Ologbon
An-NisaAtokọ Kurani
176Ẹsẹ
MedinanRevelation
109Ẹsẹ

Itumọ — An-Nisa 109

Surah An-Nisa Ẹsẹ 109 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Kiye si i, eyin wonyi ni e n ba won…

Surah Ẹsẹ 109/176 — An-Nisa النساء (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: An-Nisa Gbọ, An-Nisa Itumọ, An-Nisa mp3, An-Nisa pdf. Ẹsẹ 107–111. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers