Az-Zukhruf · 16/89
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Az-Zukhruf
أَمِ اتَّخَذَ مِمَّا يَخْلُقُ بَنَاتٍ وَأَصْفَاكُم بِالْبَنِينَ ۝١٦
Amit takhaza mimmaa yakhluqu banaatinw wa asfaakum bilbaneen
📖 Ni Yorùbá
Tabi (eyin n wi pe): "O mu ninu nnkan ti O da ni omobinrin (funra Re). O si fi awon omokunrin sa eyin lesa

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 14-18 — Surah Az-Zukhruf

14وَإِنَّا إِلَىٰ رَبِّنَا لَمُنقَلِبُونَ
Ati pe dajudaju odo Oluwa wa ni awa yoo pada si
15وَجَعَلُوا لَهُ مِنْ عِبَادِهِ جُزْءًا ۚ إِنَّ الْإِنسَانَ لَكَفُورٌ مُّبِينٌ
Won fi ipin kan ninu awon erusin (Allahu) ti si odo Re (ni ti omo bibi). Dajudaju eniyan ni alaimoore ponnbele
16أَمِ اتَّخَذَ مِمَّا يَخْلُقُ بَنَاتٍ وَأَصْفَاكُم بِالْبَنِينَ
Tabi (eyin n wi pe): "O mu ninu nnkan ti O da ni omobinrin (funra Re). O si fi awon omokunrin sa eyin lesa
17وَإِذَا بُشِّرَ أَحَدُهُم بِمَا ضَرَبَ لِلرَّحْمَٰنِ مَثَلًا ظَلَّ وَجْهُهُ مُسْوَدًّا وَهُوَ كَظِيمٌ
Nigba ti won ba fun eni kan ninu won ni iro idunnu ohun ti o fi se apeere fun Ajoke-aye (pe onitoun bi omobinrin), oju re maa sokunkun wa. O si maa kun fun ibanuje
18أَوَمَن يُنَشَّأُ فِي الْحِلْيَةِ وَهُوَ فِي الْخِصَامِ غَيْرُ مُبِينٍ
Se eni ti won n to ninu oso (ti o n to oso mora), ti ko si le bo si gbangba nibi ija (ni e n pe ni omo Ajoke-aye)
Az-ZukhrufAtokọ Kurani
89Ẹsẹ
MeccanRevelation
16Ẹsẹ

Itumọ — Az-Zukhruf 16

Surah Az-Zukhruf Ẹsẹ 16 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Tabi (eyin n wi pe): "O mu ninu nnkan ti…

Surah Ẹsẹ 16/89 — Surah Az-Zukhruf الزخرف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Az-Zukhruf Gbọ, Surah Az-Zukhruf Itumọ, Surah Az-Zukhruf mp3, Surah Az-Zukhruf pdf. Ẹsẹ 14–18. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers