Al-A'raf · 82/206
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-A'raf
وَمَا كَانَ جَوَابَ قَوْمِهِ إِلَّا أَن قَالُوا أَخْرِجُوهُم مِّن قَرْيَتِكُمْ ۖ إِنَّهُمْ أُنَاسٌ يَتَطَهَّرُونَ ٨٢
Transliteration
Wa maa kaana jawaaba qawmihee illaa an qaalooo akhrijoohum min qaryatikum innahum unaasuny yatatah haroon
Itumọ (Ni Yorùbá)
📖 Ni Yorùbá
Ki si ni o je esi ijo re bi ko se pe, won wi pe: “E le won jade kuro ninu ilu yin, dajudaju won je eniyan kan t’o n fora won mo (nibi ese).”
🎧 Gbọ
📜 Ẹsẹ 80-84 — Al-A'raf
80وَلُوطًا إِذْ قَالَ لِقَوْمِهِ أَتَأْتُونَ الْفَاحِشَةَ مَا سَبَقَكُم بِهَا مِنْ أَحَدٍ مِّنَ الْعَالَمِينَ
(Ranti Anabi) Lut, nigba ti o so fun ijo re pe: "Se e oo maa se ibaje ni ti ko si eni kan ninu awon eda t’o se iru re ri
81إِنَّكُمْ لَتَأْتُونَ الرِّجَالَ شَهْوَةً مِّن دُونِ النِّسَاءِ ۚ بَلْ أَنتُمْ قَوْمٌ مُّسْرِفُونَ
Dajudaju eyin (okunrin) n lo je adun (ibalopo) lara awon okunrin (egbe yin) dipo awon obinrin! Ani se, ijo alakoyo ni yin
82وَمَا كَانَ جَوَابَ قَوْمِهِ إِلَّا أَن قَالُوا أَخْرِجُوهُم مِّن قَرْيَتِكُمْ ۖ إِنَّهُمْ أُنَاسٌ يَتَطَهَّرُونَ
Ki si ni o je esi ijo re bi ko se pe, won wi pe: “E le won jade kuro ninu ilu yin, dajudaju won je eniyan kan t’o n fora won mo (nibi ese).”
83فَأَنجَيْنَاهُ وَأَهْلَهُ إِلَّا امْرَأَتَهُ كَانَتْ مِنَ الْغَابِرِينَ
Nigba naa, A gba oun ati ebi re la afi iyawo re ti o wa ninu awon t’o seku leyin sinu iparun
84وَأَمْطَرْنَا عَلَيْهِم مَّطَرًا ۖ فَانظُرْ كَيْفَ كَانَ عَاقِبَةُ الْمُجْرِمِينَ
A ro ojo le won lori taara. Wo bi ikangun awon elese se ri
Al-A'rafAtokọ Kurani
206Ẹsẹ
MeccanRevelation
82Ẹsẹ
Itumọ — Al-A'raf 82
Surah Al-A'raf Ẹsẹ 82 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ki si ni o je esi ijo re bi ko…Surah Ẹsẹ 82/206 — Al-A'raf الأعراف (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-A'raf Gbọ, Al-A'raf Itumọ, Al-A'raf mp3, Al-A'raf pdf. Ẹsẹ 80–84. Ni Yorùbá: العربية.
العربية
English
Bahasa Indonesia
Türkçe
Русский
فارسی
Français
اردو
বাংলা
Deutsch
Español
中文
हिन्दी
Português
Italiano
ภาษาไทย
Polski
Nederlands
Shqip
Kiswahili
O'zbek
தமிழ்
Melayu
Bosanski
Soomaali
Azərbaycan
کوردی
한국어
日本語
Svenska
Dansk
Norsk
پښتو
മലയാളം
සිංහල
Tamazight
Hausa
አማርኛ
Български
Тоҷикӣ
Қазақша
Filipino
سنڌي
Yorùbá
Fulfulde
Татарча
ئۇيغۇرچە
Кыргызча
ਪੰਜਾਬੀ
Jawa
తెలుగు
မြန်မာ
ગુજરાતી
Oromo
मराठी
Tiếng Việt
Malagasy
Нохчийн
Wolof
ދިވެހި
ಕನ್ನಡ
Українська
Ελληνικά
ქართული
ខ្មែរ
دری
Qafar af
Maranao
नेपाली
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers








