Maryam · 66/98
Itumọ Aṣẹ ohun — Maryam
وَيَقُولُ الْإِنسَانُ أَإِذَا مَا مِتُّ لَسَوْفَ أُخْرَجُ حَيًّا ۝٦٦
Wa yaqoolul insaanu `aizaa maa mittu lasawfa ukhraju haiyaa
📖 Ni Yorùbá
Eniyan n wi pe: “Se nigba ti mo ba ku, Won yoo tun mu mi jade laipe ni alaaye?”
🎧 Gbọ

📜 Ẹsẹ 64-68 — Maryam

64وَمَا نَتَنَزَّلُ إِلَّا بِأَمْرِ رَبِّكَ ۖ لَهُ مَا بَيْنَ أَيْدِينَا وَمَا خَلْفَنَا وَمَا بَيْنَ ذَٰلِكَ ۚ وَمَا كَانَ رَبُّكَ نَسِيًّا
Awa (molaika) ki i sokale ayafi pelu ase Oluwa re. TiRe ni ohun ti n be niwaju wa, ohun ti n be ni eyin wa ati ohun ti n be laaarin (mejeeji) yii. Oluwa re ki i si se onigbagbe
65رَّبُّ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ وَمَا بَيْنَهُمَا فَاعْبُدْهُ وَاصْطَبِرْ لِعِبَادَتِهِ ۚ هَلْ تَعْلَمُ لَهُ سَمِيًّا
Oluwa awon sanmo ati ile ati ohun ti n be laaarin awon mejeeji. Nitori naa, josin fun Un, ki o si se suuru lori ijosin Re. Nje o mo eni ti o tun n je oruko Re
66وَيَقُولُ الْإِنسَانُ أَإِذَا مَا مِتُّ لَسَوْفَ أُخْرَجُ حَيًّا
Eniyan n wi pe: “Se nigba ti mo ba ku, Won yoo tun mu mi jade laipe ni alaaye?”
67أَوَلَا يَذْكُرُ الْإِنسَانُ أَنَّا خَلَقْنَاهُ مِن قَبْلُ وَلَمْ يَكُ شَيْئًا
Se eniyan ko ranti pe dajudaju Awa ni A seda re teletele nigba ti ko ti i je nnkan kan
68فَوَرَبِّكَ لَنَحْشُرَنَّهُمْ وَالشَّيَاطِينَ ثُمَّ لَنُحْضِرَنَّهُمْ حَوْلَ جَهَنَّمَ جِثِيًّا
Nitori naa, mo fi Oluwa re bura; dajudaju A maa ko awon ati awon esu jo. Leyin naa, dajudaju A maa mu won wa si ayika ina Jahanamo lori ikunle
MaryamAtokọ Kurani
98Ẹsẹ
MeccanRevelation
66Ẹsẹ

Itumọ — Maryam 66

Surah Maryam Ẹsẹ 66 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Eniyan n wi pe: “Se nigba ti mo ba ku,…

Surah Ẹsẹ 66/98 — Maryam مريم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Maryam Gbọ, Maryam Itumọ, Maryam mp3, Maryam pdf. Ẹsẹ 64–68. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers