Aal-Imran · 139/200
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Aal-Imran
وَلَا تَهِنُوا وَلَا تَحْزَنُوا وَأَنتُمُ الْأَعْلَوْنَ إِن كُنتُم مُّؤْمِنِينَ ۝١٣٩
Wa laa tahinoo wa laa tahzanoo wa antumul a`lawna in kuntum mu`mineen
📖 Ni Yorùbá
E ma se kole, e si ma se banuje; eyin l’e maa leke ti e ba je onigbagbo ododo

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 137-141 — Surah Aal-Imran

137قَدْ خَلَتْ مِن قَبْلِكُمْ سُنَنٌ فَسِيرُوا فِي الْأَرْضِ فَانظُرُوا كَيْفَ كَانَ عَاقِبَةُ الْمُكَذِّبِينَ
Awon oripa kan kuku ti lo siwaju yin. Nitori naa, e rin ile lo, ki e woye si bi igbeyin awon t’o pe ododo niro se ri
138هَٰذَا بَيَانٌ لِّلنَّاسِ وَهُدًى وَمَوْعِظَةٌ لِّلْمُتَّقِينَ
Eyi ni alaye fun awon eniyan. Imona ati waasi si ni fun awon oluberu (Allahu)
139وَلَا تَهِنُوا وَلَا تَحْزَنُوا وَأَنتُمُ الْأَعْلَوْنَ إِن كُنتُم مُّؤْمِنِينَ
E ma se kole, e si ma se banuje; eyin l’e maa leke ti e ba je onigbagbo ododo
140إِن يَمْسَسْكُمْ قَرْحٌ فَقَدْ مَسَّ الْقَوْمَ قَرْحٌ مِّثْلُهُ ۚ وَتِلْكَ الْأَيَّامُ نُدَاوِلُهَا بَيْنَ النَّاسِ وَلِيَعْلَمَ اللَّهُ الَّذِينَ آمَنُوا وَيَتَّخِذَ مِنكُمْ شُهَدَاءَ ۗ وَاللَّهُ لَا يُحِبُّ الظَّالِمِينَ
Ti ipalara kan ba kan yin, iru ipalara bee kuku ti kan ijo keferi. Awon ojo wonyi, A n yi i po laaarin awon eniyan ni. Ati pe nitori ki Allahu le se afihan awon t’o gbagbo ni ododo ati nitori ki O le (tewo) gba awon t’o maa ku fun Un ninu yin. Allahu ko si nifee awon alabosi
141وَلِيُمَحِّصَ اللَّهُ الَّذِينَ آمَنُوا وَيَمْحَقَ الْكَافِرِينَ
Ati pe (o tun ri bee) nitori ki Allahu le safomo awon t’o gbagbo ni ododo ati nitori ki O le run awon alaigbagbo
Aal-ImranAtokọ Kurani
200Ẹsẹ
MedinanRevelation
139Ẹsẹ

Itumọ — Aal-Imran 139

Surah Aal-Imran Ẹsẹ 139 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : E ma se kole, e si ma se banuje; eyin…

Surah Ẹsẹ 139/200 — Surah Aal-Imran آل عمران (Medinan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Aal-Imran Gbọ, Surah Aal-Imran Itumọ, Surah Aal-Imran mp3, Surah Aal-Imran pdf. Ẹsẹ 137–141. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Monday, September 7, 2026

Don't forget us in your sincere prayers