Al-Anbiya · 109/112
Itumọ Aṣẹ ohun — Al-Anbiya
فَإِن تَوَلَّوْا فَقُلْ آذَنتُكُمْ عَلَىٰ سَوَاءٍ ۖ وَإِنْ أَدْرِي أَقَرِيبٌ أَم بَعِيدٌ مَّا تُوعَدُونَ ۝١٠٩
Fa in tawallaw faqul aazantukum `alaa sawaaa`; wa in adreee aqareebun am ba`eedum maa too`adoon
📖 Ni Yorùbá
Ti won ba gbunri, so nigba naa pe: "Emi n fi to yin leti pe emi ati eyin di jo da duro fun ogun esin (ti o maa sele laaarin wa bayii). Emi ko si mo boya ohun ti Won n se ni adehun fun yin ti sunmo tabi o si jinna

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 107-111 — Al-Anbiya

107وَمَا أَرْسَلْنَاكَ إِلَّا رَحْمَةً لِّلْعَالَمِينَ
A ko si fi ise imisi ran o bi ko se pe ki o le je ike fun gbogbo eda
108قُلْ إِنَّمَا يُوحَىٰ إِلَيَّ أَنَّمَا إِلَٰهُكُمْ إِلَٰهٌ وَاحِدٌ ۖ فَهَلْ أَنتُم مُّسْلِمُونَ
So pe: “Ohun ti Won n fi ranse si mi ni imisi ni pe, Olohun yin, Olohun Okan soso ni. Nitori naa, se eyin maa di musulumi?”
109فَإِن تَوَلَّوْا فَقُلْ آذَنتُكُمْ عَلَىٰ سَوَاءٍ ۖ وَإِنْ أَدْرِي أَقَرِيبٌ أَم بَعِيدٌ مَّا تُوعَدُونَ
Ti won ba gbunri, so nigba naa pe: "Emi n fi to yin leti pe emi ati eyin di jo da duro fun ogun esin (ti o maa sele laaarin wa bayii). Emi ko si mo boya ohun ti Won n se ni adehun fun yin ti sunmo tabi o si jinna
110إِنَّهُ يَعْلَمُ الْجَهْرَ مِنَ الْقَوْلِ وَيَعْلَمُ مَا تَكْتُمُونَ
Dajudaju (Allahu) mo ohun ti o han ninu oro. O si mo ohun ti e n fi pamo
111وَإِنْ أَدْرِي لَعَلَّهُ فِتْنَةٌ لَّكُمْ وَمَتَاعٌ إِلَىٰ حِينٍ
Emi ko si mo boya (lilo yin lara) maa je adanwo ati igbadun fun yin titi di igba die
Al-AnbiyaAtokọ Kurani
112Ẹsẹ
MeccanRevelation
109Ẹsẹ

Itumọ — Al-Anbiya 109

Surah Al-Anbiya Ẹsẹ 109 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : Ti won ba gbunri, so nigba naa pe: "Emi n…

Surah Ẹsẹ 109/112 — Al-Anbiya الأنبياء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Al-Anbiya Gbọ, Al-Anbiya Itumọ, Al-Anbiya mp3, Al-Anbiya pdf. Ẹsẹ 107–111. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers