Al-Qalam · 24/52
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Al-Qalam
أَن لَّا يَدْخُلَنَّهَا الْيَوْمَ عَلَيْكُم مِّسْكِينٌ ۝٢٤
Al laa yadkhulannahal yawma `alaikum miskeen
📖 Ni Yorùbá
pe ni oni mekunnu kan ko gbodo wonu re wa ba yin

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 22-26 — Surah Al-Qalam

22أَنِ اغْدُوا عَلَىٰ حَرْثِكُمْ إِن كُنتُمْ صَارِمِينَ
pe e ji lo si oko yin ti e ba fe ka eso
23فَانطَلَقُوا وَهُمْ يَتَخَافَتُونَ
Won lo, won si n fi ohun jeeje bara won soro
24أَن لَّا يَدْخُلَنَّهَا الْيَوْمَ عَلَيْكُم مِّسْكِينٌ
pe ni oni mekunnu kan ko gbodo wonu re wa ba yin
25وَغَدَوْا عَلَىٰ حَرْدٍ قَادِرِينَ
Won ji lo lori ero-okan kan (pe) awon lagbara
26فَلَمَّا رَأَوْهَا قَالُوا إِنَّا لَضَالُّونَ
Nigba ti won ri i, won wi pe: "Dajudaju awa ti sina
Al-QalamAtokọ Kurani
52Ẹsẹ
MeccanRevelation
24Ẹsẹ

Itumọ — Al-Qalam 24

Surah Al-Qalam Ẹsẹ 24 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : pe ni oni mekunnu kan ko gbodo wonu re wa…

Surah Ẹsẹ 24/52 — Surah Al-Qalam القلم (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Al-Qalam Gbọ, Surah Al-Qalam Itumọ, Surah Al-Qalam mp3, Surah Al-Qalam pdf. Ẹsẹ 22–26. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers