Ash-Shu'ara · 76/227
Itumọ Aṣẹ ohun — Surah Ash-Shu'ara
أَنتُمْ وَآبَاؤُكُمُ الْأَقْدَمُونَ ۝٧٦
Antum wa aabaaa`ukumul aqdamoon
📖 Ni Yorùbá
eyin ati awon baba yin isaaju

🎧 Gbọ


📜 Ẹsẹ 74-78 — Surah Ash-Shu'ara

74قَالُوا بَلْ وَجَدْنَا آبَاءَنَا كَذَٰلِكَ يَفْعَلُونَ
Won wi pe: “Rara o! A ba awon baba wa, ti won n se bee ni”
75قَالَ أَفَرَأَيْتُم مَّا كُنتُمْ تَعْبُدُونَ
(Anabi ’Ibrohim) so pe: " E so fun mi, ki ni nnkan ti e n josin fun
76أَنتُمْ وَآبَاؤُكُمُ الْأَقْدَمُونَ
eyin ati awon baba yin isaaju
77فَإِنَّهُمْ عَدُوٌّ لِّي إِلَّا رَبَّ الْعَالَمِينَ
Dajudaju awon ni ota fun mi ayafi Oluwa gbogbo eda
78الَّذِي خَلَقَنِي فَهُوَ يَهْدِينِ
(Oun ni) Eni ti O seda mi. Nitori naa, O maa fi ona mo mi
Ash-Shu'araAtokọ Kurani
227Ẹsẹ
MeccanRevelation
76Ẹsẹ

Itumọ — Ash-Shu'ara 76

Surah Ash-Shu'ara Ẹsẹ 76 - Kika, Gbọ, Itumọ, Yorùbá : eyin ati awon baba yin isaaju

Surah Ẹsẹ 76/227 — Surah Ash-Shu'ara الشعراء (Meccan). Kika Gbọ Itumọ (Yorùbá). Gbọ: Surah Ash-Shu'ara Gbọ, Surah Ash-Shu'ara Itumọ, Surah Ash-Shu'ara mp3, Surah Ash-Shu'ara pdf. Ẹsẹ 74–78. Ni Yorùbá: العربية.




Al-Kur'an


Tuesday, September 8, 2026

Don't forget us in your sincere prayers