Surah 'Abasa ni Arabic ati Yorùbá
Ka Surah 'Abasa pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (42 Ẹsẹ — مكية). 'Abasa Gbọ, 'Abasa Itumọ, 'Abasa mp3, 'Abasa pdf.Ka ati Gbọ Surah 'Abasa
🎧 Ẹsẹ
M
Mishary Rashid Alafasy
✓
Mishary Rashid Alafasy
✓
M
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
A
Abdurrahman As-Sudais
✓
Abdurrahman As-Sudais
✓
M
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
A
Abdul Basit Abdul Samad
✓
Abdul Basit Abdul Samad
✓
A
Ali Al-Hudhaify
✓
Ali Al-Hudhaify
✓
A
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
A
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
M
Muhammad Ayyoub
✓
Muhammad Ayyoub
✓
A
Abdullah Basfar
✓
Abdullah Basfar
✓
A
Abdullah Al-Juhani
✓
Abdullah Al-Juhani
✓
M
Maher Al Muaiqly
✓
Maher Al Muaiqly
✓
—
x1
وَمَا يُدْرِيكَ لَعَلَّهُ يَزَّكَّىٰ ٣
📖 Itumọ
Ẹsẹ 3
Ki si l’o maa fi mo o pe o see se ki o safomo (ara re kuro ninu aigbagbo)
أَوْ يَذَّكَّرُ فَتَنفَعَهُ الذِّكْرَىٰ ٤
📖 Itumọ
Ẹsẹ 4
tabi ki o gbo iranti, ki iranti naa si se e ni anfaani
وَمَا عَلَيْكَ أَلَّا يَزَّكَّىٰ ٧
📖 Itumọ
Ẹsẹ 7
Ko si si ese fun o bi ko ba se afomo (ara re kuro ninu aigbagbo)
وَأَمَّا مَن جَاءَكَ يَسْعَىٰ ٨
📖 Itumọ
Ẹsẹ 8
Ni ti eni ti o si wa ba o, t’o n yara gaga (si iranti, iyen afoju)
قُتِلَ الْإِنسَانُ مَا أَكْفَرَهُ ١٧
📖 Itumọ
Ẹsẹ 17
Won ti fi eniyan gegun-un (nipa) bi o se je alaimoore julo
مِن نُّطْفَةٍ خَلَقَهُ فَقَدَّرَهُ ١٩
📖 Itumọ
Ẹsẹ 19
Ninu ato l’O ti seda re. O si pebubu (eya-ara) re
كَلَّا لَمَّا يَقْضِ مَا أَمَرَهُ ٢٣
📖 Itumọ
Ẹsẹ 23
E gbo, eniyan ko ti i se nnkan ti Allahu pa lase fun un
وَفَاكِهَةً وَأَبًّا ٣١
📖 Itumọ
Ẹsẹ 31
ati awon eso (miiran) pelu ewe ti eranko n je, (A mu won hu jade)
مَّتَاعًا لَّكُمْ وَلِأَنْعَامِكُمْ ٣٢
📖 Itumọ
Ẹsẹ 32
(Won je nnkan) igbadun fun eyin ati awon eran-osin yin
لِكُلِّ امْرِئٍ مِّنْهُمْ يَوْمَئِذٍ شَأْنٌ يُغْنِيهِ ٣٧
📖 Itumọ
Ẹsẹ 37
Eni kookan won ni ojo yen l’o ti ni oran t’o maa to o o ran
وَوُجُوهٌ يَوْمَئِذٍ عَلَيْهَا غَبَرَةٌ ٤٠
📖 Itumọ
Ẹsẹ 40
Awon oju kan lojo yen ni eruku yo si bo mole
Kika Surah 'Abasa ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers

